Jump to content

Mikronésíà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Micronesia)
Micronesia
Ulithi, an atoll in the Caroline Islands.

Mikronésíà je abeagbegbe ni Oseania, to ni egbegberun awon erekusu kekeke ni apaiwoorun Okun Pasifiki. O yato si Melanesia to wa ni guusu re, ati Polynesia to wa ni ilaorun re. Awon Filipini ati Indonesia wa ni iwoorun re.