Adebo Ogundoyin
It has been suggested that this article be merged with Àdàkọ:Pagelist. (Discuss) |
Rt. Hon. Adebo Edward Ogundoyin | |
---|---|
Speaker of the Oyo State House of Assembly | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga June 2019 | |
Constituency | Ibarapa East |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejì 1987 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Olamidun Majekodunmi - Ogundoyin |
Ìyá | Justina Iyabo Ogundoyin |
Bàbá | Adeseun Oguntona Ogundoyin |
Education | Babcock University |
Occupation |
|
Adebo Edward Ogundoyin (tí wọ́n bí ní17 February 1987) jẹ́ olóṣèlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni abẹnugan ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹsàn-án ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó tún jẹ́ aṣòfin tí ń ṣojú agbègbè Ìlà-oòrùn Ìbàràpá lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú Alábùradà (Peoples Democratic Party PDP).[1][2][3][4]
Ó gba ipò ní 10 June 2019.[2]
Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adebo Edward Ogundoyin wá láti ẹkùn-ìdìbò Ìlà-oòrùn Ìbàràpá, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock (Babcock University).[5] Wọ́n dìbò yàn án láti ṣojú ẹkùn-ìdìbò Ìlà-oòrùn Ìbàràpá, wọ́n sì tún dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí abẹnugan ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin láìní alátakò, ní ọjọ́ Ajé 10 June 2019.
A second timer, he was first elected into the 8th house of Assembly in 2018 on the platform of the Peoples Democratic Party (PDP) after he won the bye-election, which was held after the death of the former Speaker, Rt. Hon. Michael Adeyemo, who died on Friday, 27 April 2018.[6]
Family background
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adebo Ogundoyin is one of the sons of the late foremost philanthropist and industrialist, Chief Adeseun Ogundoyin. He lost his father, Adeseun Ogundoyin, in 1991 at four years old. Chief Adeseun Ogundoyin, Alhaji Arisekola Alao, Chief Akanni Aluko dominated the social scene like the roaring lions dominated the jungle in Ibadan during their days.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "32-Year-Old Ogundoyin Emerges Speaker Of Oyo Assembly | Channels Television". www-channelstv-com.cdn.ampproject.org. Retrieved 10 June 2019.
- ↑ 2.0 2.1 "31-year-old Ogundoyin emerges Oyo speaker". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 June 2019.
- ↑ "PDP defeats APC in Oyo by-election". www-premiumtimesng-com.cdn.ampproject.org. Retrieved 10 June 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "PDP wins Ibarapa East State Constituency by-election". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 June 2018. Retrieved 10 June 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ University, Malam Adamu Adamu Oyo state House of AssemblyCurrent Speaker Incumbent Assumed office 10 June, 2019Personal detailsBornFebruary 18 is 31Alma mater Graduate of Babcock. "Biography of Debo Ogundoyin". Latest Nigerian News Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 16 June 2019. Retrieved 15 June 2019.
- ↑ "Behold, Adebo Ogundoyin, Nigeria’s Youngest Speaker – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-12-16.